Iwe Orin (C.M.S. 1865)

Iwe Orin 1865 97

Se olotọ títi d’ikú

Se olotọ títi d'ikú
Nigba oJọ aiye re,
Esú binu, aiye kolu,
Nwon fe gba 'o Tade re.

Se oloto ninu iyá,
Ti ko yé fi sakawe
Ayo, ogo, ati olá,

Ninu igbagbo solot,
Makun si wahala mo,
Duro ti Eni oloto,
Jesu apata re gbo.

Ninu ife se olot
Si Olúwa ore re,
Sise ife pelu ot
Sipa enikeji re.

Se olotọ ni ireti,
Gbekele Olorun re;
On kö je 'o rl ni omi
Ti iponju aiyé re.

Yio mu 'o d'ele loto
On solotQ on ifé;
Orín titun iwo okó
Nigba t'ade 'o lade.