Ogbn plorun ko dabi
Ógbon tlpgbpn t'aiyé yi,
Iran oju re se ot,
Si t'enia alaimo.
B' Olrun ga ju t'aiye Iọ,
Be 'ronu re íu ti wa lo.
Awa nfe ohun l'agbara,
Obrun yan t'ailera,
A nwo ori t'ade lade,
Olorun pe alainiye,
Ohun t'osiere loju' wa,
L'on fi datnu ologbon wa.
lyanu ju iyanu ni,
Tiwo yan eyi ti kosi,
Sugbpn otile s'iwa re,
Pe eyi, ti kö si, k'ombe,
Bi ko se be, emi na ni
Köle se okan ti re ni.
Sefefe, s'ogo, nibo ni?
T'ore ofe gbogbo ré ní;
Jesu Togbpn, on ododo,
Idande, at' isemimó
N'je, ki mma ma se ogo m,
Afi ninu Jesu mimó