Ji korin ti Mose,
T'on t'od'agutan ni,
Ji gbogbo ọkán t'on t'ede,
Yin Olugbala ni.
Yin ife iku re,
Ro ipá ajinde,
So, b'oti mbebe Torun re,
K'elese ma segbe.
Enyin ero l'ona
ílu Sion korin,
Yo ninu od agutan
Olorun; ni Kristi.
Kö pe t'aogboro ni:
Alabukun, e wá
Ofere pe wá lo nihin
Si ile Baba wa.
Nibe Tahon ayo
Ro ihin re lailai,
K'osi korin didun jul
T'odo agutan lai.