Iwe Orin (C.M.S. 1865)

Iwe Orin 1865 84

Mo f’ese mi le Jesu

Mo f'ese mi le Jesu
Odo agutan ná,
T'oru won t'osi gba wa
Ni n'eru egun na,
M'fi 'jebi mi le Jeeu,
We abawon mi mó
Eje re iyebiye
Mu gbogbo re kuro.

Mo f 'aini mi le Jesu,
Ikun ngbe ninu re,
On m'arun karun mi tan,
On gb'okán mi n'ife;
Mo f 'awe mi le Jesu,
Eru t'on t'aniyan,
Ongba mi ninu wpnyi,
On gb ekun mi kikan.

Mo f 'aiya mi le Jesu,
Aiya yi t'onsisé,
Apa re gba mi mora
Si aiya re mo te,
Mo fe oruko Jesu,
Imannel Ohiwa,
B'orun didun l'afefe,
Oruk re tan ka/

Mo fe se ge bi Jesu
Fife; 'reíe, 'rora,
Mo fe wá ge bi Jesu,
Omo mimó Baba,
Mo fe wa peíu Jesu
Larin awn loke,
Ki mb eni mimó korín
L'egbe Angel ire.