Iwe Orin (C.M.S. 1865)

Iwe Orin 1865 7

Eje kWo aiye wa ná

Eje kWo aiye wa ná,
Bwa re, ti ofi bora,
Opo ju ogo Solomon,
Tologo j'awcMi Oba o.

Sugbra ju gbogbo re lo, wo
Énia Taworan ré bo:
Emi ti Emi re ni nwon,
Ofun won n'imo at'rfgbn

Eje k'ayin Olorun wa,
Toda wa ni dara dara;
Eje ki gbogbo eda yin
Eleda, t'oto fun iyin.