Iwe Orin (C.M.S. 1865)

Iwe Orin 1865 60

Ile ayo kan wá

Ile ayo kan wá,
Ti ojina,
lle ayo, t'enia
Ðan, dan b'osan
Gbo, nwon nkorín didun:
Olugbala wa Toye,
K'awa rohin iyin re;
Yin, yin, lailai.

Wá s'ile ayo yi,
Ese niye meji!
Ese be he!
Ayo Tawa ori,
Nigba t'alai lese ri
Olugbala, t'ofun ni;
Bukun lailai.

Ile ayð ná dan,
Dan ju gbogbo,
K'omá ku ma
Njé f' ayo k'esure
Sile Oba t'oil t'ade,
T'oran j'orun lo loké,
Tao joba lai.