Iwe Orin (C.M.S. 1865)

Iwe Orin 1865 54

Jesu ngba elese sodo

Jesu ngba elese sodo
Gbo orọ itunu yi;
Enyin t'eti nyapa kuro
L'ona mimó fofisi.

Jesu gba elese sdo,
Ti ko ye fun anu re,
Sugbon owi, kamá beru,
Iru bi awa l'On fe.

Jesu gba elese sodo,
Ona ánu re l'asi,
Nigbati agutan kan nu,
Oluso re wa (a) kiri.

Kiki awon ti ko lése
Bi ti awon Parisi,
Koni ipin ninu eje,
Toti ta, fun awa, ri.

Sugbon awon ti nkerora,
Ti nkánu isina won,
Jesu gba iru wn spdo,
Osi f'igbagbo fun won.

Emi na ni Jesu ti gba
K'emi fi ogo re han,
K'erai rohin ánu ré nla
Fun elese enia.