Baba alánu t'ofe wa:
Mo gb'okán mi si o,
Apa re, t'opo, Togba wa,
Awa nkorin si 'o.
Ti re papá Tawa fé se,
Gbokán wa ni ebó,
Oda wa, osi tun wa bi,
Af 'ara wa fun 'o.
Emi Mimo wá sodg mi,
Pife Oluwa han,
Pun mi, ki emi k'ole rin
N'ife Oluwa na.
Baba alánu t'ofe wa:
Mo gb'okán mi si o,
Apa re, t'opo, Togba wa,
Awa nkorin si 'o.
Ti re papá Tawa fé se,
Gbokán wa ni ebó,
Oda wa, osi tun wa bi,
Af 'ara wa fun 'o.
Emi Mimo wá sodg mi,
Pife Oluwa han,
Pun mi, ki emi k'ole rin
N'ife Oluwa na.
Install ECWA Ikeja on your iPhoneTap the Share button in Safari, then choose Add to Home Screen.