Jesu Baba omode
Ase re ni awa nse,
Am' omo wa sodo re,
K'iwo so won di ti re.
Ninú ese Tabi won,
We won kuro lete won,
■ Eje re l'afi ra wpn,
K'ópin ebun re fun won.
gS IBAPTISMU. aM.
Bmi Olorun, wá
Baptis awon wonyi,
Majemu mímó ba won da,
We won kura lese
Fo 'pa ésu tutu
We won ni eje re,
Baba, Omo, Emi Mimó,
So won di omo re.
g4 eÍJÍ ALE OUTWk. L.ir.