Emi mimó spkaJf
Fi okun t'oriui! han,
K'pmu imole w'aiyó
Si ara enia,,
K'awa t'awá lohunkun,
Ki ole mSriran,
Bi Jesu Eristi ti ku
Fun gbogbo enia.
K'ofi han pe; elése
Ni emi nse papa
Ki emi k'olé gbeke
Mi le Olugbaía;
Nigba t'awc mi ninu
Gbogbo ese mi nu,
Emi ole fi ogo
Fun Eni mimó na.
Komu mi se aferi
Lati to Jesu lo,
K'ojoba lori emi
K'oso mi di mimo:
Ki ara ati okán,
K'odapo lati sin
Oloran Eni mimó,
Meta lokan soso.