Iwe Orin (C.M.S. 1865)

Iwe Orin 1865 26

Bi mo ba ni Jesu Kristi

Bi mo ba ni Jesu Kristi,
Emi kose alaini,
Oluso agutan mi ní,
Eni t'onipin fun ni.

On ni mu mi lo si ona
Ododo alaíia,
Ei mmo joko bi agutan
Loko tutu todara

Bi mo tile nrin lokunkun
Larin iku at'ibi,
Emi ki yiole beru,
Bi iwo ba pelu mi.

Loju gbogbo awon ota
Ti ogbe ara won ga,
Iwo nsere fun mi lara,
Atí lokán t'iwo gba.

Behe ni mo ri pe, ire,
Ati ánu t'on t'ife,
Yio to mi lehin laiye,
L'orun yio ba mi gbe.