Igbala ti Olorum wa,
Awo elese nfe,
Bi atimo pe, n'ibpgi
Mbope a kole Ía.
Ise owo ti awa nse,
Onwi nigbagbo
Pe igbala kosi nihin
A sọ ni d'ahoro.
Awa nsebo, awa nrubo,
Ankirun an nawo,
Ako ri igbala ninu
Nkan wonyi, t'osofo.
Nje tani, ti ole gba ni?
Fi han ní, íi han ni.
Ei okán wa komá fatí,
Bi t'atijo wa ri.
Jesu ni nse Olugbala,
Jesu Oluwa wa,
Of iku re ra wa pada
Ninu ese ti wa;
Si ọdo re, eje káwá,
K'aiewo ese wa,
On pe ni, wi pe: emi na
Ni ole gba ni la.