LọJọ yi ife re gba wa,
Lare Tawa lo simi,
La oru ja k' iwo gba wa,
Ninu ọta da wa si;
Jesu se olmo wa,
Le iwo lagbeke wa.
Ero at' alejo Tawa
Laiye larin ota n,
Pa awa ati t'awa mo,
Lapa re Tawa simi;
Nigba t'aiye wa opin
k'aba 'o gbe nikehin.
LọJọ yi ife re gba wa,
Lare Tawa lo simi,
La oru ja k' iwo gba wa,
Ninu ọta da wa si;
Jesu se olmo wa,
Le iwo lagbeke wa.
Ero at' alejo Tawa
Laiye larin ota n,
Pa awa ati t'awa mo,
Lapa re Tawa simi;
Nigba t'aiye wa opin
k'aba 'o gbe nikehin.
Install ECWA Ikeja on your iPhoneTap the Share button in Safari, then choose Add to Home Screen.