Iwe Orin (C.M.S. 1865)

Iwe Orin 1865 18

Mo wi fun olukuluku

Mo wi fun olukuluku
Pe, On ji osiyé,
Osi wá larin wa pelu,
Nipa Emi iyé.

Ewi fun enikeji nyin,
Ki nwon ji pelu wa,
K imole kowa kakiri
Ni gbogbo aiye wa.

Nisisiyi aiyé yi ri
Bi ile Baba wa
lyé titun ti on fun ni
Osọ (o) d'ilé Baba.

Sinu okun ti ojin ju
Iberu iku bo,
Ki gbogbo wa k'ole f oj u
. Ba nkankan ti ombo«

Ona okun ti On fi rin,
Mu ni lo si orun,
Eni t'orin bi Ön ti nrin,
Yio d'odo re lorun.

On yh, osi wá pelu wa
Ni gbogbo aiyé yi,
Ati nigba t'afara wa
F'erupe n'ireti.