Iwe Orin (C.M.S. 1865)

Iwe Orin 1865 13

NiGBA ti mo wo igi ni

NiGBA ti mo wo igi ni,
Nibi ti olugbala ku,
Ohun mí emi koka si,
Ogo mi ni mo b'egan lú.

Emi ko gbodp gbeke le,
Bikose ninu iku ré,
Ohun asan, t'on t'afe re
Mo gan, nitori eje re.

Wo! t'ori, t'owo, t'ese ré
Irora t'on tfiíe re wá,
Iru ife re kosi ri,
T'oteíe ara re fun wa.

Bi gbogbo aiye ni femi,
T'emi bun (u) Jesu, ko to nkan,
Ife ré t'aika, t aiso ri,
Gba gbogbo okán lowo wa.