K'ayin Oluwa t'ologo,
Loni Tabi (i) saiyé,
K'ayin (i) nitori ti omu
Ododo wa s'aiyé.
Awon orile ede ni
Nreti Oluwa na,
Nwon fe ri eni t'awa ri,
Ani Olugbala.
Oba ati wolí mimó
Nwon f oju si ona,
N'ireti ati igbagbo
Nwon duro d'Oluwa.
Sugbon Bni ti nwon reti,
Ani OÍugbala,
Nigba ti wa ni awa ri (i)
Anrohitt (i) y'aiye ka.