Mo dupe fun Obrun mi
Fun ihinrere na,
T'okó mi pe, of 'ese mi
S ara omo re ná.
Nwpn peran rubo nigbani,
Pe, k'om ese kuro,
Eje malú, tab' ewure
Kóle m'ese kuro.
Be l'awa enia pelu
Kóle gb' enikan la,
Bi awa ti nlese ninu
T'anwá nin' ese da.
On ti ká m6 ése k'ese
'Ani Jesu Kri'sti, '
On ná f' ese wa s'ara ré,
K'ole ra'(u) t'on febi.
Osi fi ododo re se
Wa loso nimimo,
K'amá Ig tiju, kale pé,
K'am' ododo ré wo.
Oluwa, anyin o, abe,
Pun wá rBmi mímo
K'ale wá laiye botiye
K'arin ni ododo.